ADVERTISE HERE
Awon maruun (5) lo ku, Aadota ile lo baje nipa rogbodiyan to sele ni Kogi  

  RSS
labunka
(@labunka)
Estimable Member Level5of10 Moderator
Newbie

Ko din ni eeyan Marun to ti padanu emi won ni agbegbe Aloko-Ogunma no Bassa Local Govt ni ipinle Kogi, nitori rogbodiyan to sele larin awon ara ilu Bassa Kwomu ati Igala ni Ojo Jimo 

Aadota ile no won dana sun.

ReplyQuote
Posted : 16/04/2018 11:39 am

ADVERTISE HERE

25Weeks Cash+Cards Giveaway is back on this forum-N10k Weekly To Active Members: Claim Now!

  
Working

Please Login or Register