Awon agbebon-ji-ibeji- igbakeji olubadan gbe  

  RSS
labunka
(@labunka)
Reputable Member Level6of10 Moderator
Week Winner List

Awon agbebon, ji awon ibeji ti won je omo odun marun gbe ni osan ojobo, awon omo ti o je ibeji ti Otun ti ilu ibadan, Oba Lekan Balogun, ni ile re ti o wa ni Akobo ni ilu Ibadan ipinle Oyo. Iwe iroyin Daily sun je ki a mo wipe okunrin ati obinrin ni awon ibeji naa.

http://www.oduavoice.com/blog/2018/04/15/awon agbebon-ji-ibeji- igbakeji olubadan gbe/

ReplyQuote
Posted : 15/04/2018 7:54 pm

Post in Your Native Language (Igbo,Hausa,Yoruba,Pidgin) & EARN CASH>: Click Here To Join #ProudOfNaijaLanguage FREE!

 

Place Your Ads Here (AdsSlot2)

Share:
  
Working

Please Login or Register